Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 3:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa sọ fún mi pé, “Má ṣe bẹ̀rù u rẹ̀ torí pé mo ti fi lé e yín lọ́wọ́ pẹ̀lú gbogbo ọmọ ogun rẹ̀. Bí ẹ tí ṣe sí Ṣíhónì ọba Ámórì, tí ó jọba ní Héṣíbónì ni kí ẹ ṣe sí i.”

Ka pipe ipin Deutarónómì 3

Wo Deutarónómì 3:2 ni o tọ