Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 3:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo pàṣẹ fún un yín ní ìgbà náà pé, “Olúwa Ọlọ́run yín ti fi ilẹ̀ yìí fún un yín láti ni ín. Ṣùgbọ́n, gbogbo àwọn ọkùnrin yín tí ó lera tí wọ́n sì ti dira ogun, gbọdọ̀ kọjá ṣíwájú àwọn arákùnrin yín: ará Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin Deutarónómì 3

Wo Deutarónómì 3:18 ni o tọ