Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 28:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa yóò lé ọ àti ọba tí ó yàn lóríì rẹ lọ sí orílẹ̀ èdè tí ìwọ kò mọ̀ tàbi ti àwọn baba rẹ kò mọ̀. Ibẹ̀ ni ìwọ̀ yóò sì sin ọlọ́run mìíràn, ọlọ́run igi àti òkúta.

Ka pipe ipin Deutarónómì 28

Wo Deutarónómì 28:36 ni o tọ