Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 28:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọ̀sán gangan ìwọ yóò fi ọwọ́ talẹ̀ kiri bí ọkùnrin afọ́jú nínú òkùnkùn ìwọ kì yóò ṣe àṣeyọrí nínú ohun gbogbo tí o bá ń ṣe, ojoojúmọ́ ni wọn yóò máa ni ọ́ lára àti jà ọ́ ní olè, tí kò sì ní í sí ẹnìkan láti gbà ọ́.

Ka pipe ipin Deutarónómì 28

Wo Deutarónómì 28:29 ni o tọ