Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 26:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

mú díẹ̀ nínú ohun tí o pèṣè láti inú erùpẹ̀ ilẹ̀ náà tí Olúwa Ọlọ́run rẹ ń fi fún ọ, kó wọn sínú agbọ̀n. Nígbà náà kí o lọ sí ibi tí Olúwa Ọlọ́run rẹ yóò yàn gẹ́gẹ́ bí ibi tí orúkọ rẹ̀ yóò máa gbé.

Ka pipe ipin Deutarónómì 26

Wo Deutarónómì 26:2 ni o tọ