Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 22:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó ní láti san àádọ́ta fàdákà fún baba obìnrin náà, nítorí tí ó ti bà á jẹ́. Kò lè kọ̀ ọ́ sílẹ̀ níwọ̀n ìgbà tí ó sì wà láàyè.

Ka pipe ipin Deutarónómì 22

Wo Deutarónómì 22:29 ni o tọ