Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 22:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

wọn yóò mú wá sí ẹnu ọ̀nà ilé baba rẹ̀ níbẹ̀ sì ni àwọn ọkùnrin ìlú rẹ̀ yóò ti sọ ọ́ ní òkúta pa. Ó ti ṣe ohun ìtìjú ní Isírẹ́lì nípa ṣíṣe aṣẹ́wó nígbà tí ó wà nílé baba rẹ̀. Ẹ ní láti pọ ohun búburú kúrò láàrin yín.

Ka pipe ipin Deutarónómì 22

Wo Deutarónómì 22:21 ni o tọ