Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 21:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáríjìn, Olúwa, àwọn ènìyàn rẹ ni Ísírẹ́lì, tí ìwọ ti dá sílẹ̀, àti kí ìwọ má ṣe gba ẹ̀bi ẹ̀jẹ̀ aláìsẹ̀ ní àárin àwọn ènìyàn rẹ ní Ísírẹ́lì. Ṣùgbọ́n kí a dárí ẹ̀bi ẹ̀ṣẹ̀ yìí jìn.

Ka pipe ipin Deutarónómì 21

Wo Deutarónómì 21:8 ni o tọ