Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 21:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn àlùfáà, ọmọ Léfì yóò wá ṣíwájú, nítorí Olúwa Ọlọ́run rẹ ti yàn wọ́n láti ṣe ìránṣẹ́ fún un àti láti bùkún ní orúkọ Olúwa àti láti parí gbogbo ẹjọ́ àríyànjiyàn àti ọ̀rọ̀ ìlú.

Ka pipe ipin Deutarónómì 21

Wo Deutarónómì 21:5 ni o tọ