Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 20:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

yóò sì wí pé, “Gbọ́, ìwọ Ísírẹ́lì, lónìí ò ń jáde lọ sójú ogun sí ọ̀ta rẹ. Ẹ má ṣe jẹ́ kí ọkàn yín ṣojo tàbí bẹ̀rù; ẹ má ṣe jáyà tàbí kí ẹ fi àyè fún ìjayà níwájú u wọn.

Ka pipe ipin Deutarónómì 20

Wo Deutarónómì 20:3 ni o tọ