Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 20:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ti obìnrin, àwọn ọmọdé, ohun ọ̀sìn àti gbogbo ohun tí ó kù nínú ìlú náà, o lè mú ìwọ̀nyí gẹ́gẹ́ bí ìkógún fún ara rẹ. O sì lè lo ìkógún tí Olúwa Ọlọ́run rẹ fi fún ọ láti ọ̀dọ̀ àwọn ọ̀ta rẹ.

Ka pipe ipin Deutarónómì 20

Wo Deutarónómì 20:14 ni o tọ