Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 2:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa Ọlọ́run yín ti bùkún un yín nínú gbogbo iṣẹ́ ọwọ́ ọ yín. Ó ti mójú tó ìrìnàjò yín nínú ihà ńlá yìí. Olúwa Ọlọ́run yín wà pẹ̀lú u yín ní ogojì ọdún wọ̀nyí, débi pé ẹ̀yin kò ṣaláìní ohunkóhun.

Ka pipe ipin Deutarónómì 2

Wo Deutarónómì 2:7 ni o tọ