Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 2:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó gbà wá ní ọdún méjìdínlógójì (38) kí ó tó di wí pé a la àfonífojì Sérédì kọjá láti ìgbà tí a ti kúrò ní Kadesi Báníyà. Nígbà náà gbogbo ìran àwọn tí ó jẹ́ jagunjagun láàrin àwọn ènìyàn náà ti ṣègbé kúrò láàrin àwọn ènìyàn náà ní àsìkò yìí bí Olúwa ti búra fún wọn.

Ka pipe ipin Deutarónómì 2

Wo Deutarónómì 2:14 ni o tọ