Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 18:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn àlùfáà tí wọ́n jẹ́ ọmọ Léfì, àní gbogbo ẹ̀yà Léfì, wọn kì yóò ní ìpín tàbí ogún láàrin Ísírẹ́lì, wọn yóò máa jẹ nínú ọrẹ ẹbọ tí a fi iná ṣe sí Olúwa, nítorí òun ni ogún un tiwọn.

Ka pipe ipin Deutarónómì 18

Wo Deutarónómì 18:1 ni o tọ