Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 16:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ máa yọ̀ ní àkókò àjọ̀dún un yín, ẹ̀yin, àwọn ọmọ yín ọkùnrin àti obìnrin, àwọn ẹrúkùnrin àti ẹrúbìnrin yín, àti àwọn Léfì, àwọn àjòjì, àwọn aláìní baba àti àwọn opó tí ń gbé ní àwọn ìlú u yín.

Ka pipe ipin Deutarónómì 16

Wo Deutarónómì 16:14 ni o tọ