Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 14:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ jẹ ìdámẹ́wàá, oúnjẹ yín, wáìnì tuntun, òróró, àti àkọ́bí àwọn màlúù yín àti ewúrẹ́ ẹ yín, níwájú Olúwa Ọlọ́run yín, ní ibi tí yóò yàn bí ibùgbé orúkọ rẹ̀. Kí ẹ lè kọ́ bí a ṣé ń bọlá fún Olúwa Ọlọ́run yín nígbà gbogbo.

Ka pipe ipin Deutarónómì 14

Wo Deutarónómì 14:23 ni o tọ