Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 13:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí arákùnrin tìrẹ gan-an ọmọ ìyá rẹ tàbí ọmọ rẹ ọkùnrin tàbí obìnrin, aya tí o fẹ́ràn jù, tàbí ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́ bá tàn ọ́ jẹ níkọ̀kọ̀ wí pé jẹ́ kí a lọ sin ọlọ́run mìíràn, (ọlọ́run tí ìwọ tàbí baba rẹ kò mọ̀

Ka pipe ipin Deutarónómì 13

Wo Deutarónómì 13:6 ni o tọ