Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 12:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níbi tí Olúwa Ọlọ́run yín yóò yàn bí ibùgbé fún orúkọ rẹ̀. Níbẹ̀ ni kí ẹ mú gbogbo ohun tí mo pàṣẹ fún un yín wá: àwọn ọrẹ ẹ yín àti àwọn ẹbọ síṣún, ìdámẹ́wàá yín àti ọrẹ àkànṣe, àti gbogbo ohun ìní yín tí ẹ ti yàn, èyí tí ẹ ti jẹ́jẹ̀ẹ́ fún Olúwa.

Ka pipe ipin Deutarónómì 12

Wo Deutarónómì 12:11 ni o tọ