Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 11:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí Olúwa Ọlọ́run yín ba ti mú un yín dé ilẹ̀ náà tí ẹ ń wọ̀ láti gbà, kí ẹ kéde àwọn ìbùkún náà ní orí òkè Gérísímù, kí ẹ sì kéde àwọn ègún ní orí òkè Ébálì.

Ka pipe ipin Deutarónómì 11

Wo Deutarónómì 11:29 ni o tọ