Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 1:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wò ó, èmi tí fi ilẹ̀ yí fún un yín: Ẹ wọ inú rẹ̀ lọ kí ẹ sì gba ilẹ̀ náà tí Olúwa ti wí pé òun yóò fún àwọn baba yín: fún Ábúráhámù, Ísáákì, àti Jákọ́bù, àti fún àwọn àrọ́mọdọ́mọ wọn.”

Ka pipe ipin Deutarónómì 1

Wo Deutarónómì 1:8 ni o tọ