Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 1:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ṣùgbọ́n Jósúà ọmọ Núnì tí ń ṣe olùrànlọ́wọ́ rẹ ni yóò wọ ibẹ̀. Mú un, ní ọkàn le torí pé, òun yóò ṣáájú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì láti gba ilẹ̀ náà.

Ka pipe ipin Deutarónómì 1

Wo Deutarónómì 1:38 ni o tọ