Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 1:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìgbà tí ó pé ogójì ọdún, ní ọjọ́ kìn-ín-ní osù kọ́kànlá, Mósè sọ ohun gbogbo tí Ọlọ́run pa láṣẹ nípa àwọn ọmọ Ísírẹ́lì fún wọn.

Ka pipe ipin Deutarónómì 1

Wo Deutarónómì 1:3 ni o tọ