Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 1:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níbo la ó lọ? Àwọn arákùnrin wa ti kó ìrẹ̀wẹ̀sì bá wa nípa sísọ pé, ‘Àwọn ènìyàn náà lágbára wọ́n sì ga jù wá lọ; àwọn ìlú náà tóbi jọjọ bẹ́ẹ̀ ni odi wọn ga kan ọ̀run. A tilẹ̀ rí àwọn òmìrán (Ará Ánákì) níbẹ̀.’ ”

Ka pipe ipin Deutarónómì 1

Wo Deutarónómì 1:28 ni o tọ