Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 1:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì kìlọ̀ fún àwọn onídàájọ́ yín nígbà náà pé: Ẹ gbọ́ èdè àìyedè tí ó wà láàrin àwọn ènìyàn an yín kí ẹ sì ṣe ìdájọ́ òdodo, bóyá ẹjọ́ tí ó ṣẹlẹ̀ láàrin Ísírẹ́lì sí Ísírẹ́lì ni tàbí láàrin Ísírẹ́lì kan sí àlejò.

Ka pipe ipin Deutarónómì 1

Wo Deutarónómì 1:16 ni o tọ