Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 1:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ̀nyí ni àwọn ọ̀rọ̀ tí Mósè sọ fún gbogbo Ísírẹ́lì ní ihà ìlà oòrùn Jọ́dánì, aginjù: ní òdì kejì Súfì, ní àárin Páránì àti Tófẹ́lì, Lábánì, Hásérótì àti Dísáhábì.

Ka pipe ipin Deutarónómì 1

Wo Deutarónómì 1:1 ni o tọ