Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 9:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Olúwa ìwọ ni olódodo, ṣùgbọ́n báyìí ìtìjú dé bá àwọn ènìyàn Júdà, àwọn ènìyàn Jérúsálẹ́mù àti gbogbo Ísírẹ́lì ní gbogbo orílẹ̀ èdè tí ìwọ ti fọ́n wa ká sí nítorí àìsòótọ́ ọ wa sí ọ.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 9

Wo Dáníẹ́lì 9:7 ni o tọ