Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 9:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo gbàdúrà sí Olúwa Ọlọ́run mi, mo sì jẹ́wọ́ wí pé:“Iwọ Olúwa, Ọlọ́run tí ó tóbi, tí ó sì ní ẹ̀rù, ẹni tí ń pa májẹ̀mú ìfẹ́ mọ́, pẹ̀lú àwọn tí ó ní ìfẹ́ rẹ̀ àti àwọn tí ó ń pa àwọn òfin rẹ̀ mọ́.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 9

Wo Dáníẹ́lì 9:4 ni o tọ