Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 9:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí o ṣe bẹ̀rẹ̀ sí ní gba àdúrà, a fún ọ ní ìdáhùn kan, èyí tí mo wá láti sọ fún ọ, nítorí ìwọ jẹ́ àyànfẹ́ gidigidi. Nítorí náà, gba ọ̀rọ̀ náà yẹ̀wò kí ìran náà sì yé ọ:

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 9

Wo Dáníẹ́lì 9:23 ni o tọ