Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 9:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọdun kìn-ín-ní ijọba rẹ̀, èmi Dáníẹ́lì fi iyè sí i láti inú ìwé, gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Olúwa tí wòlíì Jeremáyà, wá pé, àádọ́rin ọdún ni Jérúsálẹ́mù yóò fi wà ní ahoro.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 9

Wo Dáníẹ́lì 9:2 ni o tọ