Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 9:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa, fetí sílẹ̀! Olúwa, Dáríjìn! Olúwa, gbọ́ kí o sì ṣe é! Nítorí i tìrẹ, Ọlọ́run mi, má ṣe pẹ́ títí, nítorí ìlú rẹ àti àwọn ènìyàn rẹ ń jẹ́ orúkọ mọ́ ọ lára.”

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 9

Wo Dáníẹ́lì 9:19 ni o tọ