Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 9:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa, ní ìbámu pẹ̀lú ìwà òdodo rẹ, yí ìbínú àti ìrunú rẹ padà kúrò ní Jérúsálẹ́mù ìlú u rẹ, òkè mímọ́ rẹ. Ẹ̀ṣẹ̀ wa àti àìṣedéédé àwọn baba wa ti mú Jérúsálẹ́mù àti ènìyàn rẹ di ẹ̀gàn fún gbogbo àwọn tí ó yí wọn ká.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 9

Wo Dáníẹ́lì 9:16 ni o tọ