Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 8:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo ríi tí ó fi ìtara kọlu àgbò náà, ó lu àgbò náà bolẹ̀, ó sì ṣẹ́ ìwo rẹ̀ méjèèjì. Àgbò náà kò sì ní agbára láti dojú kọ ọ́, Òbúkọ náà kàn-án mọ́lẹ̀, ó sì fi ẹsẹ̀ tẹ̀ẹ́ mọ́lẹ̀, kò sì sí ẹni tí ó lè gba àgbò náà là kúrò lọ́wọ́ agbára rẹ̀.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 8

Wo Dáníẹ́lì 8:7 ni o tọ