Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 5:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba kígbe pé, kí wọn pe àwọn awòràwọ̀, àwọn onídán, àti àwọn aláfọ̀ṣẹ wá, ọba sì sọ fún àwọn amòye Bábílónì pé, “Ẹnikẹ́ni tí ó bá lè ka àkọsílẹ̀ yìí kí ó sì sọ ìtumọ̀ rẹ̀, ẹni náà ni a ó fi aṣọ eléṣèé àlùkò wọ̀ àti ẹ̀gbà wúrà ni a ó fi sí ọrùn un rẹ̀, òun ni yóò sì ṣe olórí kẹta ní ìjọba à mi.”

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 5

Wo Dáníẹ́lì 5:7 ni o tọ