Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 5:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n nígbà tí ọkàn rẹ̀ ga, tí ó sì le koko. Ó bẹ̀rẹ̀ sí i hùwà ìgbéraga, a mú u kúrò lórí ìtẹ́ ọba rẹ̀, a sì gba ògo rẹ̀ kúrò.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 5

Wo Dáníẹ́lì 5:20 ni o tọ