Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 5:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí Beliṣáṣárì ṣe ń mu wáìnì, ó pàṣẹ pé kí wọn kó kọ́ọ̀bù wúrà àti ti fàdákà wá, èyí tí Nebukadinéṣárì bàbá rẹ̀ kó wá láti inú tẹ́ḿpìlì ní Jérúsálẹ́mù, kí ọba àti àwọn ọlọ́lá a rẹ̀, àwọn ìyàwó àti àwọn àlè rẹ̀ kí ó ba à le fi mu wáìnì.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 5

Wo Dáníẹ́lì 5:2 ni o tọ