Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 4:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí àwọn onídán, àwọn apògèdè, àwọn awòràwọ̀ àti àwọn aláfọ̀ṣẹ wá, mo sọ àlá náà fún wọn, ṣùgbọ́n wọn kò le è sọ ìtúmọ̀ àlá náà fún mi.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 4

Wo Dáníẹ́lì 4:7 ni o tọ