Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 4:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Olùṣọ́ ni ó gbé ìpinnu náà jáde, àṣẹ sì wá láti ọ̀dọ̀ ẹni mímọ́, kí gbogbo alààyè le mọ̀ wí pé, Ọ̀gá Ògò ni olórí ìjọba ènìyàn, ó sì ń fi fún ẹnikẹ́ni tí ó wù ú, òun sì ń gbé onírẹ̀lẹ̀ lórí i wọn.’

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 4

Wo Dáníẹ́lì 4:17 ni o tọ