Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 4:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ó kígbe sókè wí pé, ‘Gé igi náà kí o sì gé àwọn ẹ̀ka rẹ̀ kúrò; gbọn ewé ẹ rẹ̀ ká, kí o sì fọ́n èṣo rẹ̀ dànù. Jẹ́ kí àwọn ẹranko tí ó wà lábẹ́ ẹ rẹ̀ sá àti àwọn ẹyẹ tí ó wà ní ẹ̀ka rẹ̀ kúrò.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 4

Wo Dáníẹ́lì 4:14 ni o tọ