Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 4:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ewé e rẹ̀ lẹ́wà, èso rẹ̀ sì pọ̀, ó sì ń pèsè oúnjẹ fún gbogbo ènìyàn. Abẹ́ ẹ rẹ̀ ni àwọn ẹranko igbó fi ṣe ibùgbé, àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run sì ń gbé ní ẹ̀ká rẹ̀, nínú rẹ̀ ni gbogbo alààyè ti ń jẹ.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 4

Wo Dáníẹ́lì 4:12 ni o tọ