Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 2:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí ẹ̀yin kò bá lè sọ àlá mi, ìjìyà kan ṣoṣo ló wà fún un yín. Ẹ̀yin ti gbèrò láti pa irọ́ àti láti sọ àwọn ọ̀rọ̀ ti ó lè ṣi ni lọ́nà fún mi, títí tí nǹkan yóò fi yí wọ́. Nítorí náà ẹ rọ́ àlá náà fún mi, èmi yóò sì mọ̀ pé ẹ lè túmọ̀ rẹ̀ fún mi.”

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 2

Wo Dáníẹ́lì 2:9 ni o tọ