Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 12:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀kan lára wọn sọ fún ọkùnrin tí ó wọ aṣọ àlà, ẹni tí ó wà lórí omi odò pé, “Báwo ni yóò ṣe pẹ́ tó kí àwọn nǹkan ìyanu wọ̀nyí tó wá sí ìmúṣẹ?”

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 12

Wo Dáníẹ́lì 12:6 ni o tọ