Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 10:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ara rẹ̀ dàbí báálì, ojú u rẹ̀ dàbí mọ̀nàmọ́ná, ẹyin ojú u rẹ̀ dàbí iná àtẹ̀tàn, apá àti ẹṣẹ̀ rẹ̀ dàbí ìtànná ìmọ́lẹ̀ tí o kún fún idẹ, àti ohùn rẹ̀ dàbí i ti ìjọ ènìyàn púpọ̀.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 10

Wo Dáníẹ́lì 10:6 ni o tọ