Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 10:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n ọmọ aládé ìjọba Páṣíà dá mi dúró fún ọjọ́mọ́kànlélógún. Nígbà náà ni Máíkẹ́lì, ọ̀kan lára ìjòyè àwọn ọmọ aládé, wá láti ràn mi lọ́wọ́, nítorí a dá mi dúró níbẹ̀ pẹ̀lú ọba Páṣíà.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 10

Wo Dáníẹ́lì 10:13 ni o tọ