Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 9:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítòótọ́ ìkà ń jóni bí iná,ó ń jó àtẹ̀wọ̀n, àtẹ̀gùn run,ó sì ń dáná sun ìgbẹ́tó bẹ́ẹ̀ tí ó fi ń yí lọ sókè ní ọ̀wọ̀n èéfín.

Ka pipe ipin Àìsáyà 9

Wo Àìsáyà 9:18 ni o tọ