Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 8:5-8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

5. Olúwa sì tún sọ fún mi pé:

6. Nítorí pé àwọn ènìyàn ti kọomi Ṣílóà tí ń ṣàn jẹ́ẹ́jẹ́ẹ́tí wọ́n sì láyọ̀ lórí Réṣínìàti ọmọ Rẹ̀málíà,

7. fún ìdí èyí, Olúwa fẹ́ mú wá sóríi wọnagbára ìkún omi odòọba Ásíríà àti ògo rẹ̀yóò sì bo gbogbo àyasíi rẹ̀gbogbo bèbè di bíbò mọ́lẹ̀

8. yóò sì gbá rìẹrìẹ dé Júdà, a gba orí ẹ̀ lọ,yóò gba ibẹ̀ lọ yóò sì mú un dọ́run.Ìyẹ́ apá rẹ̀ tí ó nà yóò bo gbogbo ìbú ilẹ̀ náàÌwọ Ìmánúẹ́lì.

Ka pipe ipin Àìsáyà 8