Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 8:15-18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

15. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ wọn ni yóò kọṣẹ̀,wọn yóò ṣubú wọn yóò sì fọ́ yángá,okùn yóò mú wọn, ọwọ́ yóò sì tẹ̀ wọ́n.”

16. Di májẹ̀mú náàkí o sì fi èdìdì di òfin náà láàrin àwọn ọmọ-ẹ̀yìn mi.

17. Èmi yóò dúró de Olúwa,ẹni tí ó ń fi ojú rẹ̀ pamọ́ fún ilé Jákọ́bù.Mo fi ìgbẹ́kẹ̀lé mi sínú rẹ.

18. Èmi nìyí, àti àwọn ọmọ tí Olúwa fi fún mi. Àwa jẹ́ àmì àti àpẹẹrẹ ní Ísírẹ́lì láti ọ̀dọ̀ Olúwa àwọn ọmọ-ogun, ẹni tí ó ń gbé ní òké Síhónì.

Ka pipe ipin Àìsáyà 8