Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 8:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa bá mi sọ̀rọ̀ pẹ̀lú ọwọ́ agbára rẹ̀ lórí mi pẹ̀lú ìkìlọ̀ fún mi pé, èmi kò gbọdọ̀ tẹ̀lé ọ̀nà àwọn ènìyàn wọ̀nyí. Ó wí pé:

Ka pipe ipin Àìsáyà 8

Wo Àìsáyà 8:11 ni o tọ