Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 7:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún àwọn òkè tí a ti ń fi ọkọ́ ro nígbà kan rí, ẹ kò ní lọ ṣíbẹ̀ mọ́ nítorí ìbẹ̀rù ẹ̀gún àti ẹ̀wọ̀n, wọn yóò di ibi tí a ń tú agbo ẹran sí, àti ibi tí àwọn àgùntàn ti ń sáré.

Ka pipe ipin Àìsáyà 7

Wo Àìsáyà 7:25 ni o tọ