Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 7:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ náà, ni gbogbo ibi tí àjàrà tí ó tó ti ẹgbẹ̀rún ṣékélì fàdákà, ẹ̀gún àti ẹ̀wọ̀n nìkan ni yóò wà níbẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 7

Wo Àìsáyà 7:23 ni o tọ