Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 7:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà, Olúwa fúnra ara rẹ̀ ni yóò fún ọ ní àmì kan. Wúndíá kan yóò lóyún, yóò sì bí ọmọkùnrin kan, yóò sì pe orúkọ rẹ̀ ní Ìmánúẹ́lì.

Ka pipe ipin Àìsáyà 7

Wo Àìsáyà 7:14 ni o tọ